• 66. "Níbo lo forúko sí tí ò njé Làmbòròkí?"
    Jul 1 2023

    Send Bidemi a Text Message!

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • “Mo mòwòn ara-à mi” kì í sèrèké èébú.
    • “Mo yó” njé “mo yó,” “mo kò” njé “mo kò;” jeun nisó, àgbà òkánjúwà ni.
    • Ng ó gba owó-ò mi lára sòkòtò yìí; ìdí àgbàlagbà nsí sílè.
    • Nlánlá lomo abuké ndá; ó ní “ìyá ìyá, òun ó pòn.”
    • Níbo lo forúko sí tí ò njé Làmbòròkí?

    For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.

    Support the Show.

    Show more Show less
    11 mins
  • 65. "“Mo mò-ó gún, mo mò-ó tè,” niyán ewùrà-á fi nlémo."
    Jun 17 2023

    Send Bidemi a Text Message!

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • “Mo gbón tán, mo mòràn tán,” kì í jé k í agbón lóró bí oyin.
    • “Mo mò-ó gùn” lesin ndà.
    • “Mo mò-ó gún, mo mò-ó tè,” niyán ewùrà-á fi nlémo.
    • Mo mò-ó tán,” l’Orò-ó fi ngbé okùnrin.
    • Mo m’òbàrà mo m’òfún,” kì í jé kí àwòko kó òpéèré nífa.

    For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.

    Support the Show.

    Show more Show less
    15 mins
  • 64. "Mélòó l’èjìgbò tí òkan è njé Ayé-gbogbo?"
    Jun 3 2023

    Send Bidemi a Text Message!

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • Mànàmáná ò séé sun isu.
    • “Bí mbá wà l’óyòó mà ti so esin;” àgùntàn-an rè á níye nílèyí.
    • Mélòó l’èjìgbò tí òkan è njé Ayé-gbogbo?
    • Mo dàgbà mo dàgó, eré omodé ò tán lójúù mi.
    • “Mo dára, mo dára,” àìdára ní npèkun è.

    For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.

    Support the Show.

    Show more Show less
    14 mins
  • 63. "Lásán kó là n dé etù; ó ní eni tórí è mbá etù mu."
    May 20 2023

    Send Bidemi a Text Message!

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • Lásán kó là n dé etù; ó ní eni tórí è mbá etù mu.
    • Lékèélékèé ò yé eyin dúdú; funfun ni wón nyé eyin won.
    • Má tèé lówó oníle, má tèé lówó àlejò; lówó ara eni la ti nté.
    • Màlúù ò lè lérí níwájú esin.
    • Láká-nláká ò séé fi làjà; omo eégún ò séé gbé seré.

    For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.

    Support the Show.

    Show more Show less
    16 mins
  • 62. "Kò-sí-nílé kì í jagun enu tì."
    May 6 2023

    Send Bidemi a Text Message!

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • Kò-sí-nílé kì í jagun enu tì.
    • Kó-tán-kó-tán lajá nlá omi.
    • Labalábá fi ara è wéye, kò lè se ìse eye.
    • Lágbájá ìbá wà a di ìjímèrè; eni tó bá níwájú di oloyo?
    • Láká-nláká ò séé fi làjà; omo eégún ò séé gbé seré.

    For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.

    Support the Show.

    Show more Show less
    15 mins
  • 61. "Kò sí mi lájo àjo ò kún: ara è ló tàn je."
    Apr 29 2023

    Send Bidemi a Text Message!

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • Kíjìpá laso òle; òfì laso àgbà; àgbà tí ò ní tòfì a rójú ra kíjìpá.
    • Kò rà, kò lówó lówó, ó nwú tutu níwájú onítumpulu.
    • Kò séni tó dùn mó, àforí eni.
    • Kò sí mi lájo àjo ò kún: ara è ló tàn je.
    • Kò sí ohun tí Sàngó lè se kó jà léèrùn.

    For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.

    Support the Show.

    Show more Show less
    16 mins
  • 60. "Kí ni ó ya àpón lórí tó fisu síná tó nsúfèé pé “bí a ti nse ni inú mbí won?”"
    Apr 15 2023

    Send Bidemi a Text Message!

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • Kí ni ìbá mú igúnugún dé òdò-o onídìrí?
    • Kí ni ó ya àpón lórí tó fisu síná tó nsúfèé pé “bí a ti nse ni inú mbí won?”
    • Kí ni onígbá nse tí aláwo ò lè se?
    • Kí ni orí nse tí èjìká ò lè se? èjìká ru erù ó gba òódúnrún; orí ta tiè ní ogúnlúgba.
    • Kí ni wón ti nse àmódù ní ìlorin? Ewúré njé béè.

    For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.

    Support the Show.

    Show more Show less
    13 mins
  • 59. "Kíni ànfàní-i kètèkètè lára kétékété à-gùn-fesè-wólè?"
    Apr 1 2023

    Send Bidemi a Text Message!

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • Kékeré l’òpòló fi ga ju ilè lo.
    • Kì í dowó-o baba kó ní ó di owó omo.
    • Kíni ànfàní-i kètèkètè lára kétékété à-gùn-fesè-wólè?
    • Kíni apárí nwá ní ìsò onígbàjámò?
    • Kíni eléwé-e-gbégbé ntà tí ó nso pé ojà ò tà?

    10 mins